adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/21.txt

1 line
663 B
Plaintext

\v 21 Nígbàtí Jésù tí re kojá sí òdì kejì, nínú ọkọ̀ ojú omi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yii ká, bí ó ti wà lẹgbẹ òkun. \v 22 Ọ̀kan nínú àwon olùdarí sínágọ́gú, ẹní tí orúkọ rẹ̀ ńjẹ́ Jáírù, ó wáà, nígbàtí ó sì ri, o wólẹ̀ níwájú rẹ̀. \v 23 Ó bẹ̀ ẹ́, ó sì tún bẹ̀ wípé, ọmọ mi obìnrin kékeré fẹ́rẹ̀ kú. Mo bẹ̀ Ọ́, wá dá ọwọ́ rẹ lee kí ó le padà bọ̀ sí pò kí o sì wà ní àláfíà. \v 24 Nítorína Ó bá lo. ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì ba lọ àti pé wọ́n súmọ́ Ó pẹ́kípẹ́kí ní agbègbè náà.