1 line
509 B
Plaintext
1 line
509 B
Plaintext
\v 18 Nígbàtí ó wọnú ọkọ̀ ojú omi lọ, ọkùnrin aláimọ́ náà bẹ̀ pé kí ohun le wà pẹ́lù rẹ. \v 19 Sùgbọ́n Jésù kò gbàá láyè, sùgbọ́n ó dá lóhùn wípé, "Lọ sí ilé rẹ àti ọ̀dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí re, kí ó royin ohun tí Olúwa tí se fún ọ àti bí ó ti fi anu han si ọ. \v 20 Ó sì lọ, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí polongo àwọn ohun ń la tí Jésù tí se fún ni agbègbé Dẹ́kápólísì, ẹnu sí yà gbogbo ènìyàn. |