adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/14.txt

1 line
441 B
Plaintext

\v 14 Àwọn tí ó fi oúnjẹ fún àwọn elẹ́dẹ̀ náà sí sálọ, wọ́n sí ròyìn ohun tí ó sẹlẹ̀ lárin ìlú àti ní gbogbo agbègbè, àwọn ènìyàn sì jáde láti rí ohun tí ó sẹlẹ̀. \v 15 Àwon ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n sì rí ọkùnrin ẹlẹ́mìí àìmọ́ náà, èyí tí ó kún fún Lígíónì, ó jóko pẹ̀lú ẹ̀wù lọ́rùn àti ọpọlọ tó yè koro.