adesinaabegunde_yo_mrk_text.../04/35.txt

1 line
450 B
Plaintext

\v 35 Ní ọjọ́ náà, nígbà tí alẹ́ lẹ́, ó wí fún wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí a rékọjá sí apá kejì.” \v 36 Wọ́n fi ọpọ̀ erò sílẹ̀, wọ́n mú Jésù pẹ̀lú wọn, gẹ́gé bí ó ti wà nínú ọkọ̀ ojú omi. Àwọn ọkọ̀ ojú omi míiràn ń bá a lọ. \v 37 Ìjì líle ńlá kan sì dìde, omi sì ń bù sínú ọkọ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ fi bẹ̀rẹ̀ sí í kún fún omi.