adesinaabegunde_yo_mrk_text.../04/30.txt

1 line
510 B
Plaintext

\v 30 Ó sì tún wí pé, “Kí ni a ò bá fi ìjọba Ọlọ́run wé, tàbí òwe wo ni a lè fi ṣe àkàwé rẹ̀? \v 31 Ó dàbí èso hóró musitadi, nígbàt ó jọ ọ̀kan nínú àwọn èso tí ó kéré jùlọ ti a gbìn sínú ilẹ̀. \v 32 Síbẹ̀, nígbà tí a gbìn ín, ó dàgbàsókè, ó gbilẹ̀, ó sì di títóbi ju gbogbo ewéko inú ọgbà yòókù lọ, ó sì yọ ẹ̀ka ńlá, tóbẹ̀ tí àwọn ẹyẹ ọ̀run lè kọ́ ìtẹ́ wọn sí ìbòji rẹ̀.