adesinaabegunde_yo_mrk_text.../03/05.txt

1 line
375 B
Plaintext

\v 5 Ó sí wò yí ká pẹ̀lú ìbínú, àti pé inú rẹ bàjẹ́ nítorí àyà líle wọn, ó sì wí fun okùnrin náà pé, "Na ọwọ́ rẹ jade." Ó sì na ọwọ́ rẹ jáde, ó sí bọ̀ sípò. \v 6 Àwọn Farisí sì jáde lojukan nàà wọn si bẹ̀rẹ̀ si gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú àwọn Olùtẹ̀lé Hẹ́ródù bí wọn ó se pa Jésù.