adesinaabegunde_yo_mrk_text.../03/03.txt

1 line
350 B
Plaintext

\v 3 Jésù sọ fún ọkùnrin tí apá rẹ rọ naa, "Dìde kí o sì dúró ni àárín àwọn ènìyàn yí." \v 4 Lẹ́hìn náà, ó bi àwọn ènìyàn naa léèré pé: Ǹjẹ́ ó bà òfin mu láti ṣerere ní ọjọ́ ìsimi tàbí ṣe búburú; lati gba ẹ̀mí là tàbí láti pa? Sùgbọ́n wọ́n dákẹ lai sọ̀rọ̀.