\v 23 Ní ọjọ́ ìsinmi, Jésù nkọjá larin àwọn oko ọkà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ si nre orí ọkà. \v 24 Àwọn Farisí sì wí fún pe, "Kíyèsíi, kí ni ó dé tí wọn nfi se èyí tí kò bá òfin mu ní ọjọ́ ìsinmi?"