adesinaabegunde_yo_mrk_text.../01/32.txt

1 line
426 B
Plaintext

\v 32 Ní àṣálẹ́, tí oòrùn ti wọ̀, wọ́n gbé gbogbo àwọn aláìsàn àti àwọn tó ni ẹ̀mí àìmọ́ tọ̀ ọ́ wá. \v 33 Gbogbo ìlú si péjọ ni ẹnu-ọ̀nà. \v 34 Ó sì wo ọ̀pọ̀ tí ó ní onírúurú ààrùn sàn, ó sì tún lé ọ̀pọ̀ ẹ̀mí àìmọ́ jáde, ṣùgbọ́n kò jẹ́ kí àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà sọ̀rọ̀ nítorí tí wọ́n mọ̀ ọ́.