adesinaabegunde_yo_mrk_text.../01/21.txt

1 line
302 B
Plaintext

\v 21 Lẹ́yìn náà wọ́n wọ Kápérnáúmù, nígbà tí ó di ọjọ́ ìsinmi, Jésù lọ sínú Sínágọ́gù ó sì ń kọ́ni. \v 22 Ẹnu sì yà wọ́n nítorí ìkọ́ni rẹ̀, nítorí pé ó ń kọ́ni bí ẹni tí ó ní àṣẹ, kì í ṣe bí àwọn olùkọ́ òfin.