adesinaabegunde_yo_mrk_text.../01/12.txt

1 line
248 B
Plaintext

\v 12 Ẹ̀mí Mímọ́ náà sì darí Rẹ̀ sí inù aginjù. \v 13 Ó sì wà ní aginjù fún ogójì ọjọ́, ti Satani ń dán an wò. Ó sì wà pẹ̀lú àwọn ẹranko ìgbẹ́, àwọn angẹli sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún un.