\v 5 "Nítorí ọkàn líle yín ni ó se kọ òfin wọ̀nyí fún yín," Jésù wí fún wọn bẹ́ẹ̀. \v 6 Ṣùgbọ́n láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ ìṣẹ̀dá, 'Ọlọ́run dá wọn ní akọ àti abo'.