\v 35 Jésù sí lọ síwájú díẹ̀, ó sì dojúbolẹ̀, ó sì gbàdúrà pé, bí ó bá se é se, kí wákàtí yìí ré kọjá kúrò lórí rẹ̀. \v 36 Ó wípé, "Abba, Bàbá, ohun gbogbo ni síse fún ọ. Mú ago yìí kúrò lórí mi. ṣùgbọ́n kì íṣe ti ìfẹ́ mi, bíkòse ti ìwọ."