\v 30 Jésù wí fún u pé, "Lõtọ ni mo wí fún ọ, lásǎlẹ́ yi, kí àkùkọ kí ó tó kọ nígbà méjì, ìwọ ô kò mí nígba mẹ́ta. \v 31 Ṣùgbọ́n Pétérù wípé, "Bí ó bá jẹ́ ti ikú pẹ̀lú rẹ, èmi kò ní sẹ́ ọ." Gbogbo wọ́n sì jẹ́jẹ̌ kannáà.