\v 35 Nítorínà, ẹ kíyèsára nítorí ẹ kò mọ àsìkò tí olórí ilé yóò padà wá ilé; ó le jẹ́ ìrọ̀lẹ́, tàbí ní àárín òru, tabi ní àfẹ̀mọ́jú, tàbí ní òwúrọ̀. \v 36 Bí ó bá dé lójijì, máṣe jẹ́ kí ó bá ọ nínú oorun. \v 37 Oun tí mo sọ fún ọ, na ni mo sọ fún gbogbo ènìyàn. Ẹ ṣọ́nà!"