diff --git a/09/07.txt b/09/07.txt index 4a05877..3408b10 100644 --- a/09/07.txt +++ b/09/07.txt @@ -1 +1 @@ -\v 7 Àwọ̀ sánmọ́ sì ṣíjibòwọ́nmọ́lẹ̀. Lọ́gán, ohùn kan jáde wá láti inú àwọ̀ọsánmọ̀n wá wípé, "Èyíyìí ni àyànfẹ́ ọmọ mi, ẹ máa gbọ́ tirẹ̀." \v 8 Bí wọ́n ti wò àyíká wọn, wọn kò rí ẹnìkankan pẹ̀lú wọn mọ́, bíkòse Jésù nìkan. \ No newline at end of file +\v 7 Àwọ̀ sánmọ́ sì ṣíjibòwọ́n mọ́lẹ̀. Lẹ́sẹ̀kẹṣè, ohùn kan jáde wá láti inú àwọ̀ọsánmọ̀ wá wípé, "Èyí ni àyànfẹ́ ọmọ mi, ẹ máa gbọ́ tirẹ̀." \v 8 Bí wọ́n ti wò àyíká wọn, wọn kò rí ẹnìkankan pẹ̀lú wọn mọ́, bíkòṣe Jésù nìkan. \ No newline at end of file