Tue May 18 2021 21:38:39 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 21:38:39 +01:00
parent 748e688270
commit f3f981e575
3 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1,2 +1 @@
\v 33 Òun lo ọ̀pọ̀ irú òwe wọ̀nyí láti ba àwọn ènìyàn sọrọ̀, gẹ́gẹ́ bí wọ́n bá ti ní òye tó, \v 34 kò sì bá wọn sọ̀rọ̀ láì lo òwe. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó dá wa bá sì wà pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, òun a sì sọ ìtumọ̀ ohun gbogbo.
Jesu mú afẹ́fẹ́ okun dákẹ́ jẹ́ẹ́
\v 33 Òun lo ọ̀pọ̀ irú òwe wọ̀nyí láti ba àwọn ènìyàn sọrọ̀, gẹ́gẹ́ bí wọ́n bá ti ní òye tó, \v 34 kò sì bá wọn sọ̀rọ̀ láì lo òwe. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó dá wà, ó sàlàyé gbọgbọ rẹ̀ fún àwọn ọmọ ẹyìn rẹ̀.

1
04/35.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 35 Ní ọjọ́ náà, nígbà tí alẹ́ lẹ́, ó wí fún wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí a rékọjá sí apá kejì.” 36Nígbà tí wọn ti tú ìjọ ká, wọ́n sì gbà á sínú ọkọ̀ ojú omi gẹ́gẹ́ bí ó ti wà. Àwọn ọkọ̀ ojú omi kékeré mìíràn sì wà lọ́dọ̀ rẹ̀. 37Ìjì líle ńlá kan sì dìde, omi sì ń bù sínú ọkọ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ fi bẹ̀rẹ̀ sí í kún fún omi, ó sì fẹ́rẹ rì. \v 36 \v 37 ss

View File

@ -68,6 +68,7 @@
"04-21",
"04-24",
"04-26",
"04-30"
"04-30",
"04-33"
]
}