Thu May 20 2021 13:06:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 13:06:12 +01:00
parent 159c3c3c99
commit f3b31d3600
3 changed files with 4 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 7 Wọ́n tún ní àwọn ẹja wẹ́wẹ́ díẹ̀ pẹ̀lú, lẹ́yìn tí ó dúpẹ́, ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti pín wọn fún àwọn ènìyàn náà. 10Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, lẹ́yìn èyí, Jesu wọ inú ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì gúnlẹ̀ sí agbègbè Dalmanuta.\v 8 Wọ́n jẹun wọ́n sì yó, wọ́n kó àjẹkù ti ó kù jọ, agbọ̀n méje sì kún. \v 9 Àwọn tí ó wà níbẹ̀ tó ìwọ̀n ẹgbàajì ènìyàn. Ó sì rán wọn lọ. \v 10 ss
\v 7 Wọ́n tún ní àwọn ẹja wẹ́wẹ́ díẹ̀ pẹ̀lú, lẹ́yìn tí ó dúpẹ́, ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti pín wọn fún àwọn ènìyàn náà. \v 8 Wọ́n jẹun wọ́n sì yó, wọ́n kó àjẹkù ti ó kù jọ, agbọ̀n méje sì kún. \v 9 Àwọn tí ó wà níbẹ̀ tó ìwọ̀n ẹgbàajì ènìyàn. Ó sì rán wọn lọ. \v 10 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó wọ inú ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì lọ sí agbègbè Dalmanuta.

1
08/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 NÍgbà náà ni àwọn Farisi tọ Jesu wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí béèrè ìbéèrè lọ́wọ́ rẹ̀. Láti dán an wò, wọ́n béèrè fún ààmì láti ọ̀run. 12Jesu mí kanlẹ̀, nígbà tí ó gbọ́ ìbéèrè wọn. Ó sì dáhùn wí pé, “Èéṣe tí ìran yìí fi ń wá ààmì? Lóòótọ́ ni mo sọ fún un yín kò si ààmì tí a ó fi fún ìran yín.” 13Nígbà náà ni ó padà sínú ọkọ̀ ojú omi ó fi àwọn ènìyàn sílẹ̀, ó sì rékọjá sí apá kejì Òkun náà.\v 12 \v 13 ss

View File

@ -75,6 +75,7 @@
"04-40",
"08-title",
"08-01",
"08-05"
"08-05",
"08-07"
]
}