Mon Nov 25 2019 05:10:38 GMT-0800 (Pacific Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-11-25 05:10:39 -08:00
parent 9e6738824a
commit ef9c0cbd14
3 changed files with 2 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 53 Wọ́n sì mú Jẹ́sù lọ ṣọ́dọ̀ olórí àlùfáà. Gbogbo àwọn olórí àlùfàà, àti àwọn àgbàgbà, àti àwọn akọ̀wé sì péjọ pẹ̀lú rẹ̀. \v 54 Pétérù sì n tọ̀ ọ́ lẹ́yìn ní òkèrè wọ̀ inú ilé, títí wọ́ fi dé àgbàlá olóri àlúfà. Ó sì bá àwọn ẹ̀sọ́ jókǒ, tí wọ́n ńyáná.
\v 53 Wọ́n sì mú Jẹ́sù lọ ṣọ́dọ̀ olórí àlùfáà. Gbogbo àwọn olórí àlùfàà, àti àwọn àgbàgbà, àti àwọn akọ̀wé sì péjọ pẹ̀lú rẹ̀. \v 54 Pétérù sì n tọ̀ ọ́ lẹ́yìn ní òkèrè wọ̀ inú ilé, títí wọ́n fi dé àgbàlá olóri àlùfáà. Ó sì bá àwọn ẹ̀sọ́ jókǒ, tí wọ́n ń yáná.

View File

@ -1 +1 @@
\v 55 Nígbànáà ni àwọn olórí àlùfá àti gbogbo àjọ ìgbìmọ̀ Jew ńwá ẹ̀rí sí Jesu láti pa á. Wọn kò sì rí ohun kan. \v 56 Nítorípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó jẹ́rǐ èké sí i, ṣùgbọ́n ohùn àwọn ẹlẹ́rǐ náà kò ṣọ̀kan.
\v 55 Nígbànáà ni àwọn olórí àlùfá àti gbogbo àjọ ìgbìmọ̀ júù ńwá ẹ̀rí l sí Jesu láti pa á. Wọn kò sì rí ohun kan. \v 56 Nítorípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó jẹ́rǐ èké sí i, ṣùgbọ́n ohùn àwọn ẹlẹ́rǐ náà kò ṣọ̀kan.

View File

@ -57,7 +57,6 @@
"14-43",
"14-47",
"14-51",
"14-55",
"14-57",
"14-60",
"14-63",