From eab7b6474ed0691334410e1073c86d8dec63702a Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Thu, 16 May 2019 11:39:57 +0100 Subject: [PATCH] Thu May 16 2019 11:39:56 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 07/24.txt | 2 +- 07/27.txt | 2 +- manifest.json | 2 +- 3 files changed, 3 insertions(+), 3 deletions(-) diff --git a/07/24.txt b/07/24.txt index aa1e201..54e41a2 100644 --- a/07/24.txt +++ b/07/24.txt @@ -1 +1 @@ -\v 24 Ó sì dìde kúrò níbẹ̀, Ó sì lọ sí agbègbè Tírè àti Sídónì. Ó wọ inú ilé kan, kò sì fẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀ pé Òun wà níbẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò le sápamọ́n fún wọn. \v 25 Sùgbọ́n lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, obìnrin kan tí ọmọ rè ní ẹ̀mí àìmọ́, gbọ́ nípa rẹ̀, ó wá, ó sì kúnlẹ̀ sílẹ̀ ní ibi ẹsẹ̀ rẹ̀. \v 26 Ara Gíríkì ni obìnrin náà ń se, ọmọ bíbí Sirofẹ́níkà níí se. Ó bẹ Jésù kí ó bá òun lé ẹ̀mí èsù inú ọmọbìnrin òun jáde. \ No newline at end of file +\v 24 Ó sì dìde kúrò níbẹ̀, Ó sì lọ sí agbègbè Tírè àti Sídónì. Ó wọ inú ilé kan, kò sì fẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀ pé Òun wà níbẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò le sápamọ́n fún wọn. \v 25 Ṣùgbọ́n lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, obìnrin kan tí ọmọ rè ní ẹ̀mí àìmọ́, gbọ́ nípa rẹ̀, ó wá, ó sì kúnlẹ̀ sílẹ̀ ní ibi ẹsẹ̀ rẹ̀. \v 26 Ara Gíríkì ni obìnrin náà ń se, ọmọ bíbí Sirofẹ́níkà níí se. Ó bẹ Jésù kí ó bá òun lé ẹ̀mí èsù inú ọmọbìnrin òun jáde. \ No newline at end of file diff --git a/07/27.txt b/07/27.txt index 82e0a88..5903ff4 100644 --- a/07/27.txt +++ b/07/27.txt @@ -1 +1 @@ -\v 27 Jésù wí fún un pé, "Jẹ́ kí àwọn ọmọ ilé Ísrẹ́lì kọ́kọ́ jẹhun ná, nítorípé kò dára kí á wá lọ gbé ohunjẹ àwọn ọmọ kí á lọ gbée fún àwọn kéfèrí." \v 28 Sùgbọ́n Obìnrin yìí dáhùn, ó wí fún Jésù pé, "Bẹ́ẹ̀ni, Olúwa, àwọn kèfèrí pàápàá le jẹ ẹ̀rúnrún ohúnjẹ àwọn ọmọ Ísrẹ́lì tí ó bá bọ́ sí ilẹ̀ láti oríi tábìlì." \ No newline at end of file +\v 27 Jésù wí fún un pé, "Jẹ́ kí àwọn ọmọ ilé Ísrẹ́lì kọ́kọ́ jẹhun ná, nítorípé kò dára kí á wá lọ gbé ohunjẹ àwọn ọmọ kí á lọ gbée fún àwọn kéfèrí." \v 28 Ṣùgbọ́n Obìnrin yìí dáhùn, ó wí fún Jésù pé, "Bẹ́ẹ̀ni, Olúwa, àwọn kèfèrí pàápàá le jẹ ẹ̀rúnrún ohúnjẹ àwọn ọmọ Ísrẹ́lì tí ó bá bọ́ sí ilẹ̀ láti oríi tábìlì." \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 72eb0a7..c8253ea 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -44,9 +44,9 @@ "07-11", "07-14", "07-17", + "07-20", "07-24", "07-27", - "07-29", "07-31", "07-33", "07-36"