Tue May 18 2021 11:48:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 11:48:48 +01:00
parent 3e0edd3eb5
commit e64e7a376a
1 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1,2 @@
\v 32 \v 33 \v 34 dd
\v 32 Ní àṣálẹ́, tí oòrùn ti wọ̀, wọ́n gbé gbogbo àwọn aláìsàn àti àwọn tó ni ẹ̀mí àìmọ́ tọ̀ ọ́ wá. \v 33 Gbogbo ìlú si péjọ ni ẹnu-ọ̀nà. \v 34 Ó sì wo ọ̀pọ̀ tí wọ́n ní onírúurú ààrùn sàn. Bákan náà ni ó lé ọ̀pọ̀ ẹ̀mí àìmọ́ jáde, Ṣùgbọ́n kò sì jẹ́ kí àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà kí ó sọ̀rọ̀, nítorí tí wọ́n mọ ẹni tí òun í ṣe.
Jesu ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ láti gbàdúrà