From e5a12eee014a037d752352c296123ed4c0299b47 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Fri, 9 Jul 2021 10:00:41 +0100 Subject: [PATCH] Fri Jul 09 2021 10:00:41 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 10/46.txt | 2 +- 10/49.txt | 2 +- manifest.json | 1 + 3 files changed, 3 insertions(+), 2 deletions(-) diff --git a/10/46.txt b/10/46.txt index a89b97f..8ce81bc 100644 --- a/10/46.txt +++ b/10/46.txt @@ -1 +1 @@ -\v 46 Wọ́n wá sí Jẹ́ríkò. Bí ó se fi Jẹ́ríkò sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò, ọmọ Tíméaù, Bátólóméù afọ́jú tí ó ntọrọ, jókòó ní ẹ̀bá ọ̀nà. \v 47 Nígbàtí ó gbọ́ pé Jésù ti Násárẹ́tì ni, ó bẹ̀rẹ̀ síi kígbe wípé, "Jésù ọmọ Dáfídì sàánú fún mi". \v 48 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló bá afọ́jú náà wí, pé kí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́. Ṣùgbọ́n ó kígbe lóhùn rara síi "ọmọ Dáfídì sàánú fún mi" \ No newline at end of file +\v 46 Wọ́n wá sí Jẹ́ríkò. Bí ó se fi Jẹ́ríkò sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò, ọmọ Tíméaù, Bátólóméù afọ́jú tí ó ntọrọ, jókòó ní ẹ̀bá ọ̀nà. \v 47 Nígbàtí ó gbọ́ pé Jésù ti Násárẹ́tì ni, ó bẹ̀rẹ̀ síi kígbe wípé, "Jésù ọmọ Dáfídì sàánú fún mi". \v 48 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló bá afọ́jú náà wí, pé kí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́. Ṣùgbọ́n ó kígbe lóhùn rara síi "ọmọ Dáfídì sàánú fún mi!" \ No newline at end of file diff --git a/10/49.txt b/10/49.txt index 99b9173..2da3803 100644 --- a/10/49.txt +++ b/10/49.txt @@ -1 +1 @@ -\v 49 Jésù dúró ó sì pàsẹ pé kí wọ́n pèé wá. Wọ́n pe ọkùnrin afọ́jú náà, Ó ńpè ọ́ se bi akin! dìde! Ó ńpè ọ́." \v 50 Ó ju asọ rẹ̀ sí apákan ó dìde wá sọ́dọ̀ Jésù \ No newline at end of file +\v 49 Jésù dúró ó sì pàsẹ pé kí wọ́n pèé wá. Wọ́n pe ọkùnrin afọ́jú náà, Ó ńpè ọ́ se bi akin! dìde! Ó ńpè ọ́." \v 50 Ó ju asọ rẹ̀ sí apákan ó dìde wá sọ́dọ̀ Jésù. \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index a644743..3659cad 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -231,6 +231,7 @@ "10-38", "10-41", "10-43", + "10-46", "10-49", "10-51", "11-01",