From e2f4e1b3a269af73cd95a750d4c7a1bba9c990da Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Thu, 20 May 2021 15:18:13 +0100 Subject: [PATCH] Thu May 20 2021 15:18:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 12/32.txt | 5 ++--- 12/35.txt | 8 ++++++++ manifest.json | 3 ++- 3 files changed, 12 insertions(+), 4 deletions(-) create mode 100644 12/35.txt diff --git a/12/32.txt b/12/32.txt index ef8cdb9..398f1e8 100644 --- a/12/32.txt +++ b/12/32.txt @@ -1,3 +1,2 @@ -\v 32 Olùkọ́ òfin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ pé Ọlọ́run kan ni ó wà, àti pé kò sí òmíràn lẹ́yìn rẹ̀. -\v 33 Àti kí a fi gbogbo ọkàn, àti gbogbo òye, àti agbára fẹ́ ẹ, àti fẹ́ ọmọnìkejì ẹni bí ara ẹni, ó ju gbogbo ẹbọ sísun, àti ẹbọ lọ.” \v 34 Nígbà tí Jesu rí i dájú pé ó ti dáhùn pẹ̀lú òye, Ó wí fún un pé, “Ìwọ kò jìnà sí ìjọba Ọ̀run.” Láti ìgbà náà lọ, ẹnikẹ́ni kò tún béèrè ohun kan lọ́wọ́ Jesu. -Ọmọ ta ni Kristi ń ṣe? \ No newline at end of file +\v 32 Olùkọ́ òfin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ pé Ọlọ́run kan ni ó wà, àti pé kò sí òmíràn lẹ́yìn rẹ̀. +\v 33 Àti kí a fi gbogbo ọkàn, àti gbogbo òye, àti agbára fẹ́ ẹ, àti fẹ́ ọmọnìkejì ẹni bí ara ẹni, ó ju gbogbo ẹbọ sísun, àti ẹbọ lọ.” \v 34 Nígbà tí Jesu rí i dájú pé ó ti dáhùn pẹ̀lú òye, Ó wí fún un pé, “Ìwọ kò jìnà sí ìjọba Ọlọ́run.” Láti ìgbà náà lọ, ẹnikẹ́ni kò tún béèrè ohun kan lọ́wọ́ Jesu. \ No newline at end of file diff --git a/12/35.txt b/12/35.txt new file mode 100644 index 0000000..9ae768b --- /dev/null +++ b/12/35.txt @@ -0,0 +1,8 @@ +\v 35 Jesu dáhùn nígbà tí ó ń kọ́ ni nínú tẹ́ḿpílì, ó béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Èéṣe tí àwọn olùkọ́ òfin fi gbà wí pé Kristi náà ní láti jẹ́ ọmọ Dafidi? 36Nítorí tí Dafidi tìkára rẹ̀, ti ń ti ipa Ẹ̀mí Mímọ́ sọ̀rọ̀ wí pé: +“ ‘Olúwa sọ fún Olúwa mi pé: +“Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi, +títí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀tá rẹ +di àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.” ’ +37 Níwọ́n ìgbà tí Dafidi tìkára rẹ̀ pè é ní ‘Olúwa,’ Báwo ni ó túnṣe lè jẹ́ ọmọ rẹ̀?” +Ọ̀pọ̀ ènìyàn sì fi ayọ̀ gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀. +\v 36 \v 37 dd \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index b3cf070..c0b7a8a 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -102,6 +102,7 @@ "12-20", "12-24", "12-26", - "12-28" + "12-28", + "12-32" ] } \ No newline at end of file