Fri Nov 08 2019 20:59:46 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
EDUNOLAOLUWA 2019-11-08 20:59:47 +01:00
parent c509183563
commit e0f0e58ac4
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 16 Sùgbọ́n nígbàt´ Hẹ́rọ́dù gbọ́ èyií, ó wípé "Jòhánù tí mo gé orí rẹ̀, ti jí dìde." \v 17 Nítorí Hẹ́rọ́dù ránṣẹ́ láti mú Jòhánù, ó sì jú sẹ́wọ̀n nítorí Hẹrodia, aya arakunrin re Filipi ti o yan lale.
\v 16 Sùgbọ́n nígbàt´ Hẹ́rọ́dù gbọ́ èyií, ó wípé "Jòhánù tí mo gé orí rẹ̀, ti jí dìde." \v 17 Nítorí Hẹ́rọ́dù ránṣẹ́ láti mú Jòhánù, ó sì jú sẹ́wọ̀n nítorí Hẹrodíà, aya arákùnrin rẹ̀ Fílípì tí ó yàn lálè.

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Nitori Johanu ba Herodu wi, "pe ko tona lati yan aya arakunrin re lale." \v 19 Herodia si binu si Johanu, o si n wa ona lati pa a, eyi si nira fun \v 20 nitori Herodu beru Johanu. Ati wipe o mo pe olododo ati eniyan mimo ni, o si pa a mo. Gbigbo oro re ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo.
\v 18 Nítorí Jòhánù bá Hẹ́rọ́dù wí, "pé ko tona lati yan aya arakunrin re lale." \v 19 Herodia si binu si Johanu, o si n wa ona lati pa a, eyi si nira fun \v 20 nitori Herodu beru Johanu. Ati wipe o mo pe olododo ati eniyan mimo ni, o si pa a mo. Gbigbo oro re ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo.

View File

@ -42,7 +42,7 @@
"06-10",
"06-12",
"06-14",
"06-18",
"06-16",
"06-21",
"06-23",
"06-26",