From de6533d27f5be8f6e4d688bda6101313cbc4db2e Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Thu, 16 May 2019 15:37:19 -0900 Subject: [PATCH] Thu May 16 2019 15:37:18 GMT-0900 (Alaskan Standard Time) --- 10/46.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/10/46.txt b/10/46.txt index 020a695..a89b97f 100644 --- a/10/46.txt +++ b/10/46.txt @@ -1 +1 @@ -\v 46 Wọ́n wá sí Jẹ́ríkò. Bí ó se fi Jẹ́ríkò sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò, ọmọ Tíméaù, Bátólóméù afọ́jú tí ó ntọrọ, jókòó ní ẹ̀bá ọ̀nà. \v 47 Nígbàtí ó gbọ́ pé Jésù ti Násárẹ́tì ni, ó bẹ̀rẹ̀ síi kígbe wípé, "Jésù ọmọ Dáfídì sàánú fún mi". \v 48 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló bá afọ́jú náà wí, pé kí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́. Sùgbọ́n ó kígbe lóhùn rara síi "ọmọ Dáfídì sàánú fún mi" \ No newline at end of file +\v 46 Wọ́n wá sí Jẹ́ríkò. Bí ó se fi Jẹ́ríkò sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò, ọmọ Tíméaù, Bátólóméù afọ́jú tí ó ntọrọ, jókòó ní ẹ̀bá ọ̀nà. \v 47 Nígbàtí ó gbọ́ pé Jésù ti Násárẹ́tì ni, ó bẹ̀rẹ̀ síi kígbe wípé, "Jésù ọmọ Dáfídì sàánú fún mi". \v 48 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló bá afọ́jú náà wí, pé kí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́. Ṣùgbọ́n ó kígbe lóhùn rara síi "ọmọ Dáfídì sàánú fún mi" \ No newline at end of file