Mon Nov 25 2019 05:02:38 GMT-0800 (Pacific Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-11-25 05:02:39 -08:00
parent f186eba7f6
commit dad104623b
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 47 Ṣùgbọ́n ọ̀kan lára àwọn tí ó sún mọ́ wọn yọ idà rẹ̀ ó sì fi gé etí ọmọ-ọ̀dọ̀ olórí àlùfáà. \v 48 Jésù sì wí fún wọn pé, "Sé ẹ̀yin jáde wá gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó fé mú olè ni, pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀ láti wá mú mi? \v 49 Nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín nígbàgbogbo tí mo sì ń kọ́ yín ní témpílì, ẹ̀yin kò mú mi. Ṣùgbọ́n a se èyí kí á le mú ọ̀rọ̀-mímọ́ se." \v 50 gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lu Jesu sì fi sílẹ wọ́n sì sáré kúrò.
\v 47 Ṣùgbọ́n ọ̀kan lára àwọn tí ó sún mọ́ wọn yọ idà rẹ̀ ó sì fi gé etí ọmọ-ọ̀dọ̀ olórí àlùfáà. \v 48 Jésù sì wí fún wọn pé, "Sé ẹ̀yin jáde wá gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó fé mú olè ni, pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀ láti wá mú mi? \v 49 Nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín nígbà gbogbo tí mo sì ń kọ́ yín ní témpílì, ẹ̀yin kò mú mi. Ṣùgbọ́n a se èyí kí á le mú ọ̀rọ̀-mímọ́ sẹ." \v 50 gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lu Jésù sì fií sílẹ̀ wọ́n sì sá lọ.