Tue May 18 2021 20:42:42 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
1d768c2663
commit
d28d56ac46
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 16 Èyí ni àwọn tí ó bọ́ sórí àpáta, nígbà tí wọ́n bá gbọ́ ọrọ̀ náà, lójúkanánáà wọ́n fi ayọ̀ gbà á. \v 17 Ṣùgbọ́n wọn kò ni gbòǹgbò nínú u wọn, Ṣùgbọ́n wọ́n á wà fún ìgbà díẹ̀, lẹ́yìn náà nígbà ti wàhálà tàbí inúnibíni bá dìde nítorí ọ̀rọ̀ náà, lójúkan náà, wọ́n á kọsẹ̀.
|
||||
\v 16 Èyí ni àwọn tí ó bọ́ sórí àpáta, nígbà tí wọ́n bá gbọ́ ọrọ̀ náà, lójúkanánáà wọ́n fi ayọ̀ gbà á. \v 17 Ṣùgbọ́n wọn kò ni gbòǹgbò nínú u wọn, Ṣùgbọ́n wọ́n faradàá fún ìgbà díẹ̀. Lẹ́yìn náà ni wàhálà tàbí inúnibíni dìde nítorí ọ̀rọ̀ náà, lójúkan náà, wọ́n subú.
|
|
@ -0,0 +1,3 @@
|
|||
\v 18 Àwọn tí ó kù bọ́ sáàrín ẹ̀gún ni àwọn tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, tí wọn sì gbà á. 19Ṣùgbọ́n láìpẹ́ jọjọ, àwọn adùn ayé àti inú dídùn, ọrọ̀ àti ìjàkadì fún àṣeyọrí àti ìfẹ́ àwọn ohun mèremère ayé, gba ọkàn wọn, wọ́n sì fún ọ̀rọ̀ náà pa ní ọkàn wọn. Ọ̀rọ̀ náà sì jẹ́ aláìléso. 20Ṣùgbọ́n àwọn tí ó bọ́ sí ilẹ̀ ọlọ́ràá, ní àwọn tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí wọ́n sì gbà á lóòtítọ́, wọ́n sì mú èso púpọ̀ jáde fún Ọlọ́run ní ọgbọọgbọ̀n, ọgọọgọ́ta, àti òmíràn ọgọọgọ́rùn-ún, gẹ́gẹ́ bí a ti gbìn ín sí ọkàn wọn.”
|
||||
Àtùpà lórí ọ̀pá fìtílà
|
||||
\v 19 \v 20 dd
|
|
@ -62,6 +62,7 @@
|
|||
"04-06",
|
||||
"04-08",
|
||||
"04-10",
|
||||
"04-13"
|
||||
"04-13",
|
||||
"04-16"
|
||||
]
|
||||
}
|
Loading…
Reference in New Issue