Fri May 17 2019 05:01:04 GMT-1200 (Dateline Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 05:01:30 -12:00
parent 151c2d57df
commit d162227b8c
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 11 O si se ọpọlọpọ awọn ẹlẹdẹ si jẹun lori oke, \v 12 Wọn si bẹẹ, wipe, "Ran wa lo si nu agbo ẹlẹdẹ; jẹ ka wọ inu wọn lọ." \v 13 O si gba wọn laye; awọn ẹmi aimọ naa si jade, wọn si wọnu awọn agbo ẹlẹdẹ lọ, wọn si sare sokale lọ sinu okun, bi ẹgbẹrun meji ẹlẹdẹ si parun sinu okun.
\v 11 Ó sì se, agbo awọn ẹlẹ́dẹ̀ si jẹun lori oke, \v 12 Wọn si bẹẹ, wipe, "Ran wa lo si nu agbo ẹlẹdẹ; jẹ ka wọ inu wọn lọ." \v 13 O si gba wọn laye; awọn ẹmi aimọ naa si jade, wọn si wọnu awọn agbo ẹlẹdẹ lọ, wọn si sare sokale lọ sinu okun, bi ẹgbẹrun meji ẹlẹdẹ si parun sinu okun.