Tue May 14 2019 22:17:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-14 22:17:13 +01:00
parent 64f7df6c07
commit c2242d21db
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 5 O si wo yi ka pẹlu ìbínú, ati pe inu rẹ bajẹ nitorii àyà líle wọn, o si wi fun okùnrin naa pe, "Na ọwọ́ rẹ jade." O si na wo re jade, o si bo sipo. \v 6 Awon Farisi si jade lojukan naa won si bere si gbimo po pelu awon Olutele Herodu bi won o se pa Jesu.
\v 5 O si wo yi ka pẹlu ìbínú, ati pe inu rẹ bajẹ nitorii àyà líle wọn, o si wi fun okùnrin naa pe, "Na ọwọ́ rẹ jade." O si na ọwọ́ rẹ jade, o si bọ sipo. \v 6 Awọn Farisi si jade lojukan naa wọn si bẹrẹ si gbimọ pọ pẹlu awọn Olutẹle Hrodu bi won o se pa Jesu.