Tue Feb 27 2018 12:41:58 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2018-02-27 12:41:58 +01:00
parent 8248b9d112
commit c0b451d9ca
3 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 21 Anfani lati pa a wa nigbati Oba Herodu se ojo ibi, osi se ase fun awon emewa re, awon alase ati awon adari ni ile Galili. \v 22 Omobirin Herodia si wa fi ijo da Herodu ati awon alejo re laraya. Oba Herodu si wipe fun omo na pe: bere ohnu ti o ba fe ni owo mi, emi o si fi fun o?
\v 21 Anfani lati pa a wa nigbati Oba Herodu se ojo ibi, osi se ase fun awon emewa re, awon alase ati awon adari ni ile Galili. \v 22 Omobirin Herodia si wa fi ijo da Herodu ati awon alejo re laraya. Oba Herodu si wipe fun omobirin na pe: "bere ohun kohun ti o ba fe ni owo mi, emi o si fi fun o."

View File

@ -1 +1 @@
\v 23 \v 24 \v 25 Herodu si bura fun odomobirin na pe ohun ti o ba fe titi de idaji ijoba ohun ni n o fifun o. Omobirin yi sare lo bere lowo iya re wipe; ki ni kin bere? Herodia si ipe, bere ori Johanu. Omo si sare pada wa oni fun mi nisisiyi ori johanu sinu awo ti mo gbe wa yi.
\v 23 Herodu si bura fun odomobirin na pe, "ohun kohun ti o ba fe titi de idaji ijoba ohun ni n o fifun o. \v 24 Omobirin yi sare lo bere lowo iya re wipe; ki ni kin bere? Herodia si ipe, bere ori Johanu. \v 25 Omo si sare pada wa oni fun mi nisisiyi ori johanu sinu awo ti mo gbe wa yi.

View File

@ -43,6 +43,7 @@
"06-12",
"06-14",
"06-16",
"06-18"
"06-18",
"06-21"
]
}