Thu May 20 2021 13:00:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 13:00:12 +01:00
parent d9071d15c8
commit bfe9dee7e8
3 changed files with 4 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 5 Jesu béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “ìṣù àkàrà mélòó lẹ ní lọ́wọ́?” Wọ́n wípé, “Méje.” \v 6 Ó pàṣẹ fún ọ̀pọ ènìyàn náà láti jókòó lórí ilẹ̀. Ó mú àkàrà méje náà, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run, ó sì bù wọ́n sí wẹ́wẹ́, ó pín wọn fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ láti gbé ka iwájú àwọn ènìyàn, wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀.
\v 5 Jesu béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “ìṣù àkàrà mélòó lẹ ní lọ́wọ́?” Wọ́n wípé, “Méje.” \v 6 Ó pàṣẹ fún ọ̀pọ ènìyàn náà láti jókòó lórí ilẹ̀. Ó mú àkàrà méje náà, ó dúpẹ́, ó sì bù wọ́n sí wẹ́wẹ́. Ó fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti gbé sí iwájú àwọn ènìyàn, wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀.

1
08/07.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 7 Wọ́n tún ní àwọn ẹja wẹ́wẹ́ díẹ̀ pẹ̀lú, Jesu tún dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run fún ìpèsè náà, ó sì pàṣẹ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ láti pín wọn fún àwọn ènìyàn náà. 8Gbogbo ọ̀pọ̀ ènìyàn náà ló jẹ àjẹyó àti àjẹtẹ́rùn. Lẹ́yìn èyí wọ́n kó àjẹkù ti ó kù jọ, agbọ̀n méje sì kún. 9Àwọn tí ó jẹ ẹ́ tó ìwọ̀n ẹgbàajì (4,000) ènìyàn, ó sì rán wọn lọ. 10Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, lẹ́yìn èyí, Jesu wọ inú ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì gúnlẹ̀ sí agbègbè Dalmanuta.\v 8 \v 9 \v 10 ss

View File

@ -74,6 +74,7 @@
"04-38",
"04-40",
"08-title",
"08-01"
"08-01",
"08-05"
]
}