Thu May 16 2019 12:19:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:19:35 +01:00
parent 0e6adf1b88
commit be9f7aa9ef
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 17 Ẹnìkan láàrín èrò sì dáhùn ó wípé, "Olùkó, mo mú ọmọ mi tọ̀ Ọ́ wá.Ẹ̀míkẹ́mìí kan ti jẹ́ kó ya odi \v 18 O' gbáá mú, ó sì gbée sánlẹ̀, bẹ́ẹ̀ni ó mún kí ó máa yọ èfó lẹ́nu, ó payín keke, , ó sì le púpọ̀. Mo bẹ àwọn ọmọ èyìn re kí wọ́n leèle jáde sùgbọ́n wọn kò lee sé." \v 19 Ó sì wí fun wọn pé, "Ìran aláìgbàgbọ́, èmi ó ti bá n yín gbé pẹ́ tó? Èmi ó ti mún sùúrù pẹ́ tó fún n yín? Mú n wá fún mi.?"
\v 17 Ẹnìkan láàrín èrò sì dáhùn ó wípé, "Olùkó, mo mú ọmọ mi tọ̀ Ọ́ wá.Ẹ̀míkẹ́mìí kan ti jẹ́ kó ya odi \v 18 Ó má ń gbáa mú, á sì gbée sánlẹ̀, bẹ́ẹ̀ni ó má ń mú kí ó máa pòfóló, yọ èfó lẹ́nu, ó payín keke, , ó sì le púpọ̀. Mo bẹ àwọn ọmọ èyìn re kí wọ́n leèle jáde sùgbọ́n wọn kò lee sé." \v 19 Ó sì wí fun wọn pé, "Ìran aláìgbàgbọ́, èmi ó ti bá n yín gbé pẹ́ tó? Èmi ó ti mún sùúrù pẹ́ tó fún n yín? Mú n wá fún mi.?"