Tue May 18 2021 11:22:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 11:22:48 +01:00
parent 2cea1c7b53
commit be5462f970
3 changed files with 6 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 16 Nígbà ti ó ń rìn létí Òkun Galili, Ó rí Simoni àti Anderu arákùnrin rẹ̀, wọ́n ń fi àwọ̀n wọn pẹja, torí pé apẹja ni wọ́n. \v 17 Jesu sì wí fún wọn pé, “Ẹ wa, ẹ tẹ̀lé mi, Èmi yóò sì sọ yín di apẹja ènìyàn.” \v 18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tẹ
\v 16 Nígbà ti ó ń rìn létí Òkun Galili, Ó rí Simoni àti Anderu arákùnrin rẹ̀, wọ́n ń fi àwọ̀n wọn pẹja, torí pé apẹja ni wọ́n. \v 17 Jesu sì wí fún wọn pé, “Ẹ wa, ẹ tẹ̀lé mi, Èmi yóò sì sọ yín di apẹja ènìyàn.” \v 18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tẹ̀lé e.

3
01/19.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,3 @@
\v 19 19Bí Ó sì ti rìn síwájú díẹ̀, ní etí Òkun, Ó rí Jakọbu ọmọ Sebede àti Johanu arákùnrin rẹ̀ nínú ọkọ̀, wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe. 20Ó sì ké sí àwọn náà lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, wọ́n fi Sebede baba wọn sílẹ̀ nínú ọkọ̀ pẹ̀lú àwọn alágbàṣe, wọ́n sì tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.
Jesu lé ẹ̀mí àìmọ́ jáde
\v 20 ff

View File

@ -43,6 +43,7 @@
"01-07",
"01-09",
"01-12",
"01-14"
"01-14",
"01-16"
]
}