Tue May 14 2019 15:15:43 GMT-1200 (Dateline Standard Time)
This commit is contained in:
parent
c98c8f4dfa
commit
bc2c476ff0
|
@ -1 +1 @@
|
||||||
\v 39 Nigbati o si wọ ile naa, o wi fun wọn wipe, "Ki lode ti ẹ banujẹ ti ẹ ṣin sọkun? Ọmo naa ko ku, sugbọn o sun." \v 40 Wọn si fi rẹrin. Sugbọn o ti gbogbo wọn si ta. O si mu baba omo na, iya omo naa ati awọn ti o wa pelu re, o si wọle si ibi ti ọmọ naa wa.
|
\v 39 Nigbati o si wọ ile naa, o wi fun wọn wipe, "Ki lode ti ẹ banujẹ ti ẹ ṣin sọkun? Ọmọ naa ko ku, sugbọn o sun." \v 40 Wọn si fi rẹrin. Sugbọn o ti gbogbo wọn si ta. O si mu baba omo na, iya omo naa ati awọn ti o wa pelu re, o si wọle si ibi ti ọmọ naa wa.
|
|
@ -1 +1 @@
|
||||||
\v 41 O si mu owo omo naa o si wi fun wipe, "Talitha Koum!" eyi ti o tumo si wipe, "omobinrin, mo wi fun o, dide." \v 42 Loju kana, omo naa dide, o si rin (O je omo odun mejila nigbana). Lesekanna enu ya won iberu bojo si bo okan won. \v 43 O si pase fun won wipe, enikeni ko gbodo mo ni pa re. O si wi fun won wipe, ki won fun loje je.
|
\v 41 O si mu ọwọ ọmọ naa o si wi fun wipe, "Talitha Koum!" eyi ti o tumọ si wipe, "ọmọbinrin, mo wi fun ọ, dide." \v 42 Loju kana, ọmọ naa dide, o si nrin (O je ọmọ ọdun mejila nigbana). Lẹsẹkanna ẹnu ya won iberu bojo si bo okan won. \v 43 O si pase fun won wipe, enikeni ko gbodo mo ni pa re. O si wi fun won wipe, ki won fun loje je.
|
Loading…
Reference in New Issue