diff --git a/10/43.txt b/10/43.txt index d0a5b02..c61c9ee 100644 --- a/10/43.txt +++ b/10/43.txt @@ -1 +1 @@ -\v 43 Sùgbọ́n kò gbọdọ̀ rí bẹ́ẹ̀ láàrín yín. Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ di gíga nínú yín yóò se ọmọ ọ̀dọ̀, \v 44 àti ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ se asájú nínú yín yóò se ìránsẹ́ gbogbo won. \v 45 Nítorí ọmọ ènìyàn kò wá pé kí á se ìránsẹ́ fún òun bíkòse láti se ìránsẹ́ fún ẹlòmiran ati lati yonda ara re fun irapada opolopo." \ No newline at end of file +\v 43 Sùgbọ́n kò gbọdọ̀ rí bẹ́ẹ̀ láàrín yín. Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ di gíga nínú yín yóò se ọmọ ọ̀dọ̀, \v 44 àti ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ se asájú nínú yín yóò se ìránsẹ́ gbogbo won. \v 45 Nítorí ọmọ ènìyàn kò wá pé kí á se ìránsẹ́ fún òun bíkòse láti se ìránsẹ́ fún ẹlòmíràn àti láti yònda ara rẹ̀ fún ìràpàdà opolopo" \ No newline at end of file