Fri May 17 2019 09:45:31 GMT-1200 (Dateline Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 09:45:32 -12:00
parent df60a2bedb
commit b93ef90475
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 26 Obìnrin kan sí wá ní bẹ tí o ní isun ẹ̀jẹ̀ fún ọdún méjìla. \v 25 O ti ní orísirisi ìlàkọjá pẹ̀lú àwon onísègùn àti pé ó ti ná ohun gbogbo tí óní, sùgbọ́n, kàkà kí o sàn se ló ń le koko si. \v 27 Nígbàtí o sì gbó ìròyìn nípa Jésù, Ò sí tò wá larin àwon ero, O duro leyin re, O si fi ọwọ kan eti asọ rẹ.
\v 26 Obìnrin kan sí wá ní bẹ tí o ní isun ẹ̀jẹ̀ fún ọdún méjìla. \v 25 O ti ní orísirisi ìlàkọjá pẹ̀lú àwon onísègùn àti pé ó ti ná ohun gbogbo tí óní, sùgbọ́n, kàkà kí o sàn se ló ń le koko si. \v 27 Nígbàtí o sì gbó ìròyìn nípa Jésù, Ò sí tò wá larin àwon èrò, Ò dúró lẹ́yìn rẹ̀, O si fi ọwọ kan eti asọ rẹ.