Tue May 18 2021 11:58:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 11:58:48 +01:00
parent 7c68723946
commit b521acab17
3 changed files with 6 additions and 4 deletions

View File

@ -1,3 +1 @@
\v 38 Ó wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a lọ sí àwọn ibò mìíràn, sí àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè, kí ń lè wàásù níbẹ̀ pẹ̀lú. Nítorí èyí ni èmi sá à ṣe wá.” 39Nítorí náà, ó ń kiri gbogbo agbègbè Galili, ó ń wàásù nínú Sinagọgu. Ó sì ń lé àwọn ẹ̀mí àìmọ́ jáde.
Ọkùnrin tí o ní ààrùn ẹ̀tẹ̀
\v 39 dd
\v 38 Ó wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a lọ sí àwọn ibò mìíràn, sí àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè, kí ń lè wàásù níbẹ̀ pẹ̀lú. Nítorí èyí ni mo ṣe wá.” \v 39 Ó ń lọ káàkiri gbogbo agbègbè Galili, ó ń wàásù nínú Sinagọgu Ó sì ń lé àwọn ẹ̀mí àìmọ́ jáde.

3
01/40.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,3 @@
\v 40 Ọkùnrin adẹ́tẹ̀ kan tọ̀ ọ́ wá. sì kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀. Ó sì bẹ̀bẹ̀ fún ìmúláradá. Ó wí pé, “Bí ìwọ bá fẹ́, ìwọ lè mú mi láradá.”
41Jesu kún fún àánú, ó na ọwọ́ rẹ̀, ó fi ọwọ́ rẹ̀ bà a, ó wí pé, “Èmí fẹ́. Di mímọ́.” 42Lójúkan náà ẹ̀tẹ̀ náà fi sílẹ̀ lọ, ọkùnrin náà sì rí ìwòsàn.
\v 41 \v 42 ss

View File

@ -51,6 +51,7 @@
"01-27",
"01-29",
"01-32",
"01-35"
"01-35",
"01-38"
]
}