Fri Nov 08 2019 21:53:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
EDUNOLAOLUWA 2019-11-08 21:53:47 +01:00
parent 4c396b6335
commit b4e48b8110
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 26 Bó tilẹ̀ jẹ́ wípé èyí ba ọba nínú jẹ́, kò le sa láì mú ìbéèrè rẹ̀ se nítorí tí óti búra fún un àti nítorí àwọn àlejò rẹ̀. \v 27 Ọba rán àwọn emèwà rẹ̀ kí wọ́n lọ bẹ́ orí Jòhánù wá. Ẹmẹ̀wà náà sì lọ bẹ́ orí Jòhánù láti inú ọgbà ẹ̀wọ̀n wá \v 28 Ósì gbẹ́ fún ọ̀dọ́mọbirin náà nínú igbá, ọmọbìrin náà sì lọ gbè e fún iya re. \v 29 Nigbati awon omoleyin re gbo, won lo gbe ara re toku lo si iboji.
\v 26 Bó tilẹ̀ jẹ́ wípé èyí ba ọba nínú jẹ́, kò le sa láì mú ìbéèrè rẹ̀ se nítorí tí óti búra fún un àti nítorí àwọn àlejò rẹ̀. \v 27 Ọba rán àwọn emèwà rẹ̀ kí wọ́n lọ bẹ́ orí Jòhánù wá. Ẹmẹ̀wà náà sì lọ bẹ́ orí Jòhánù láti inú ọgbà ẹ̀wọ̀n wá \v 28 Ósì gbẹ́ fún ọ̀dọ́mọbirin náà nínú igbá, ọmọbìrin náà sì lọ gbè e fún ìya rẹ̀. \v 29 Nígbàtí àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ gbọ́, wọ́n lọ gbé ara rẹ̀ tókù lọ sí ibojì.