diff --git a/16/14.txt b/16/14.txt index fe33d76..6c4efb6 100644 --- a/16/14.txt +++ b/16/14.txt @@ -1 +1 @@ -\v 14 Jésù sì tún farahàn fún àwọn mọ́kànlá bí wọ́n tí ń jẹun lórí tábìlì, ó sì bá wọn wí fún àìgbàgbọ́ àti líle àyà wọn, nítorí wọn kò gba àwọn tí ó kọ́kọ́ rí i, lẹ́yìn tí ó jí dìde gbọ́. \v 15 Ó sọ fún wọn pé, Ẹlo sí gbogbo ayé kí ẹlọ wásù ìhìnrere fún gbogbo ẹ̀dá. \v 16 Ẹnikẹ́ni tí ó bà gbàgbọ́ tí a sì baptisí rẹ̀ ni a ó gbàlà,àti ẹnikẹ́ni tí kò bá gbàgbọ́ a ó dá a lẹ́jọ́. \ No newline at end of file +\v 14 Jésù sì tún farahàn fún àwọn mọ́kànlá bí wọ́n tí ń jẹun lórí tábìlì, ó sì bá wọn wí fún àìgbàgbọ́ àti líle àyà wọn, nítorí wọn kò gba àwọn tí ó kọ́kọ́ rí i, lẹ́yìn tí ó jí dìde gbọ́. \v 15 Ó sọ fún wọn pé, "Ẹ lọ sí gbogbo ayé kí ẹ lọ wáásù ìhìnrere fún gbogbo ẹ̀dá. \v 16 Ẹnikẹ́ni tí ó bà gbàgbọ́ tí a sì baptisí rẹ̀ ni a ó gbàlà,àti ẹnikẹ́ni tí kò bá gbàgbọ́ a ó dá a lẹ́jọ́. \ No newline at end of file