Wed Nov 27 2019 12:23:15 GMT-0800 (Pacific Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-11-27 12:23:15 -08:00
parent 5042e8fbae
commit b1ec1df796
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Jésù sì tún farahàn fún àwọn mọ́kànlá bí wọ́n tí ń jẹun lórí tábìlì, ó sì bá wọn wí fún àìgbàgbọ́ àti líle àyà wọn, nítorí wọn kò gba àwọn tí ó kọ́kọ́ rì ì lẹ́yìn tí ó jí dìde gbọ́. \v 15 Ó sọ fún wọn pé, Ẹlo sí gbogbo ayé kí ẹlọ wásù ìhìnrere fún gbogbo ẹ̀dá. \v 16 Ẹnikẹ́ni tí ó bà gbàgbọ́ tí a sì baptisí rẹ̀ ni a ó gbàlà,àti ẹnikẹ́ni tí kò bá gbàgbọ́ a ó dá a lẹ́jọ́.
\v 14 Jésù sì tún farahàn fún àwọn mọ́kànlá bí wọ́n tí ń jẹun lórí tábìlì, ó sì bá wọn wí fún àìgbàgbọ́ àti líle àyà wọn, nítorí wọn kò gba àwọn tí ó kọ́kọ́ rí i, lẹ́yìn tí ó jí dìde gbọ́. \v 15 Ó sọ fún wọn pé, Ẹlo sí gbogbo ayé kí ẹlọ wásù ìhìnrere fún gbogbo ẹ̀dá. \v 16 Ẹnikẹ́ni tí ó bà gbàgbọ́ tí a sì baptisí rẹ̀ ni a ó gbàlà,àti ẹnikẹ́ni tí kò bá gbàgbọ́ a ó dá a lẹ́jọ́.