Tue May 14 2019 13:38:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-14 13:38:35 +01:00
parent 633259f027
commit acc872a003
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 20 Wọ́n mú ọmọkùnrin náà wá sọ́dọ̀ rẹ̀, nígbàtí ẹ̀mí náà rí Jésù, ó lulẹ̀ ó sì dàkú lójijì. Ọmọkùnrin náà subúlulẹ̀ ósì yọ èfó lẹ́nu rẹ̀. \v 21 Jésù bá bi bàbá ọmọ náà, "Ó ti pẹ́ tó tí ti wà nírú ipò yìí?" Bàbá rẹ̀ dáhùn ówípé, "Láti ìgb` èwe rẹ̀ ni. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, \v 22 ó tilẹ̀ má n gbe jù sínú iná tàbí sínú omi láti paá lára nígbàmíràn. Bí o bá le se ohunkóhun, sàánú fún wa kí o si ranwalowo."
\v 20 Wọ́n mú ọmọkùnrin náà wá sọ́dọ̀ rẹ̀, nígbàtí ẹ̀mí náà rí Jésù, ó lulẹ̀ ó sì dàkú lójijì. Ọmọkùnrin náà subúlulẹ̀ ósì yọ èfó lẹ́nu rẹ̀. \v 21 Jésù bá bi bàbá ọmọ náà, "Ó ti pẹ́ tó tí ti wà nírú ipò yìí?" Bàbá rẹ̀ dáhùn ówípé, "Láti ìgb` èwe rẹ̀ ni. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, \v 22 ó tilẹ̀ má n gbe jù sínú iná tàbí sínú omi láti paá lára nígbàmíràn. Bí o bá le se ohunkóhun, sàánú fún wa kí o sì rànwálọ́wọ́."

View File

@ -1 +1 @@
\v 23 Jesu wi funn pe, "Bi iwo ba lee se, ohun gbogb ni sise fun awon ti o gbagbo." \v 24 Lojukanna, baba omo naa kigbe soke wipe, "Mo gbagbo! Ran aigbagbo mi lowo." \v 25 Nigbati Jesu ri opo ero to n wa sodo re, O ba emi aimo naa wi o wipe, "Iwo emi odi ati iditi, mo pase fun o, jade kuro lara re ki o ma sise pada sibe mo."
\v 23 Jésù wí fún pé, "Bí ìwọ bá le se, ohun gbogb ni sise fun awon ti o gbagbo." \v 24 Lojukanna, baba omo naa kigbe soke wipe, "Mo gbagbo! Ran aigbagbo mi lowo." \v 25 Nigbati Jesu ri opo ero to n wa sodo re, O ba emi aimo naa wi o wipe, "Iwo emi odi ati iditi, mo pase fun o, jade kuro lara re ki o ma sise pada sibe mo."