Wed May 26 2021 12:31:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-26 12:31:44 +01:00
parent 99a6ddbca8
commit a50b79509d
2 changed files with 1 additions and 3 deletions

View File

@ -1,2 +1 @@
\v 32 Olùkọ́ òfin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ pé Ọlọ́run kan ni ó wà, àti pé kò sí òmíràn lẹ́yìn rẹ̀. \v 32 Olùkọ́ òfin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ pé Ọlọ́run kan ni ó wà, àti pé kò sí òmíràn lẹ́yìn rẹ̀. \v 33 Àti kí a fi gbogbo ọkàn, àti gbogbo òye, àti agbára fẹ́ ẹ, àti fẹ́ ọmọnìkejì ẹni bí ara ẹni, ó ju gbogbo ẹbọ sísun, àti ẹbọ lọ.” \v 34 Nígbà tí Jesu rí i dájú pé ó ti dáhùn pẹ̀lú òye, Ó wí fún un pé, “Ìwọ kò jìnà sí ìjọba Ọlọ́run.” Láti ìgbà náà lọ, ẹnikẹ́ni kò tún béèrè ohun kan lọ́wọ́ Jesu.
\v 33 Àti kí a fi gbogbo ọkàn, àti gbogbo òye, àti agbára fẹ́ ẹ, àti fẹ́ ọmọnìkejì ẹni bí ara ẹni, ó ju gbogbo ẹbọ sísun, àti ẹbọ lọ.” \v 34 Nígbà tí Jesu rí i dájú pé ó ti dáhùn pẹ̀lú òye, Ó wí fún un pé, “Ìwọ kò jìnà sí ìjọba Ọlọ́run.” Láti ìgbà náà lọ, ẹnikẹ́ni kò tún béèrè ohun kan lọ́wọ́ Jesu.

View File

@ -105,7 +105,6 @@
"12-28", "12-28",
"12-32", "12-32",
"12-35", "12-35",
"12-38",
"12-41", "12-41",
"12-43" "12-43"
] ]