Fri Nov 22 2019 02:55:28 GMT-0800 (Pacific Standard Time)
This commit is contained in:
commit
9dffc9881c
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 37 Ó padà wá, oó sì rí wọn tí wọn n sùn, ó sì wí fún Peteru, "Simoni, ìwọ ń sùn bi? Ìwọ kò ha le sọ́nà fún wákàtí kan? \v 38 Ẹ máa sọ́nà kí e sì ma gbàdúrà kí ẹ̀yin kí ó má baà bọ́ sínú ìdánwò. Ẹ̀mí ń fẹ́ nítòótọ́, ṣùgbọ́n ó se àìlera fún ara." \v 39 Ó sì tún lọ kúrò ní ọ̀dọ̀ wọn láti lọ gbàdúrà, ó sì tún lo ọ̀rọ̀ kanńà.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 40 Ó sì tún bá wọn tí wọn ń sùn, nítorí tí ojú wọn wúwo wọn kó sí mọ ohun tí wọn yí ò sọ fún n. \v 41 Ó sì wá ní ìgbà kẹta ó sì wí fún wọn pé, " Sé ẹ̀yin sí n sùn ni? Ó ti tó! Wákàtí náà ti dé. Wò ó! Ati fi ọmọ ènìyàn lé àwọn elésè lọ́wọ́. \v 42 Ẹ dìde; ẹ jẹ́kí a lọ. Wó ò, ẹni tí yíò dà mí ti wà nítòsí."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 43 Nígbàtí ó sì ń sọ̀rọ̀, Judasi, ọ̀kan nínú àwọn méjìlá, dé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sí wà pẹ̀lú rẹ̀ pẹ̀lú idà àti ọkọ̀, láti ọ̀dọ̀ olórí àlúfà, àwọn akòwè, àti àwọn àgbà. \v 44 7777 ẹni tí yí ò dà á ti fún wọn ní àmì, wípé, " Enikéni tí òun bá fi ẹnu kò ní ẹnu, òun ni. Ẹ mú u lọ." \v 45 Nígbàtí Judasi sì dé, lójúkanńà ó tọ Jesu wá ó sì wípé, "Rabbi," ó sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu. \v 46 Wọ́n sì mú u.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 47 Ṣùgbọ́n ọ̀kan lára wọn tí ó sún mọ́ wọn yo idà rẹ̀ ó sì fi gé etí ọmọ-ọ̀dọ̀ olórí àlúfà. \v 48 Jésù sí wí fún wọn pé, "Sé ẹ̀yin jáde wá gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó lòdì sí olè ni, pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀ láti wá mú mi? \v 49 Nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín nígbàgbogbo tí mo sì ń kọ́ yín ní témpílì, ẹ̀yin kò mú mi. Ṣùgbọ́n a se èyí kí á le mú ọ̀rọ̀-mímọ́ se." \v 50 gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lu Jesu sì fi sílẹ wọ́n sì sáré kúrò.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 51 kan, ti o wo aso ogbo nikan, si n tele Jesu.Nigba ti won si mu Jesu, \v 52 o fi aso ogbo naa sile, o si sa kuro ni ihoho.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 53 Wọn si mu Jesu lọ ṣọdọ olori alufa. gbogbo awọn olori alufa, ati awọn agbagba, ati awọn akọwe si pejọ pẹlu rẹ̀. \v 54 Peteru si tọ̀ ọ lẹhin li òkere wọ̀ inu ile, titi fi de agbala olori alufa; o si bá awọn eso joko, ti won nyána.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 56 \v 55 Nigbanaa ni awọn olori alufa ati gbogbo ajọ ìgbimọ Jew nwá ẹri si Jesu lati pa a. Wọn kò si ri ohun kan.\v 56 Nitoripe ọ̀pọlọpọ li o jẹri eke si i, ṣugbọn ohùn awọn ẹlẹri na kò ṣọkan.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 58 \v 57 Awọn kan si dide, nwọn njẹri eke si i, won wipe, Awa gbọ́ ti o un so wipe, Emi ó wó tẹmpili yi ti a fi ọwọ́ ṣe, ni wọn ijọ́ mẹta emi o si kọ́ omiran ti akò fi ọwọ́ se \v 59 Sibe eri won ko sokan.
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 60 Olori alufa si dide laarin won o si bi Jesu lere wipe, Iwo ko ni idahun bi, kini ohin ti awon eniyan yin jeri lodi si o?
|
||||
\v 61 O si dake, ko si so ohunkohun. Olori alufa si bi ilere wipe, se iwo ni Kristi omo olubukun? \v 62 Jesu wipe Emi ni, iwo yio si ri omo eniyan nigbati o ba joko ni apa otun agbara ti o si wa ni awosanmo."
|
|
@ -0,0 +1,5 @@
|
|||
\v 63
|
||||
Eyintigbooroeganna.Kinieyin fe se fun n? Gbogbo won si kegan re gege bi eni ti o ye fun iku.
|
||||
|
||||
Awonmiranberesinitutosiilarawonsiboojurewonsiluwonwifunpe,sotele! Awon omo ogun si mu u won si lu.
|
||||
\v 64 \v 65 cc
|
|
@ -0,0 +1,4 @@
|
|||
\v 66 Bi Peteru si ti wà ni isalẹ li ãfin, ọkan ninu awọn ọmọbinrin olori alufa wá si odo re.
|
||||
[67]O ri Peteru ti o nyána, o wò o, o si wipe, Iwọ wa pẹlu Jesuara Nasareti yi.
|
||||
[68]Ṣugbọn o sẹ́, wipe, Emi ko mọ̀, oyé ohun ti iwọ nso kò tilẹ yé mi. O si jade lọ si iloro; akukọ si kọ.
|
||||
\v 67 \v 68 ccc
|
|
@ -0,0 +1,3 @@
|
|||
\v 69 Ọmọbinrin na si tún ri i, o si bẹ̀rẹ si iwi fun awọn ti o duro nibẹ̀ pe, Ọkan ninu wọn ni okunrin yi.
|
||||
[70]O si tún sẹ́. O si tun pẹ diẹ, awọn ti o duro nibẹ̀ tún wi fun Peteru pe, Lõtọ ni, ọkan ninu wọn ni iwọ iṣe: nitoripe ara Galili ni iwọ, ède rẹ si jọ bẹ̃.
|
||||
\v 70 xx
|
|
@ -0,0 +1,4 @@
|
|||
\v 71 Ṣugbọn o bẹ̀rẹ si ni fi ara re re o si bura wipe, "Emi ko mọ̀ ọkunrin yi ẹniti ẹnyin nwi.
|
||||
[72]Lojukanna akukọ si kọ ni igba keji. Peteru si ranti ọrọ ti Jesu wi fun u pe, Ki akukọ ki o to kọ leemeji , iwo o sẹ́ mi lẹemẹta. Nigbati o si rò o, o sọkun.
|
||||
|
||||
\v 72 cc
|
|
@ -34,7 +34,8 @@
|
|||
"parent_draft": {},
|
||||
"translators": [
|
||||
"Tobyno88",
|
||||
"adegokeaanuoluwapo"
|
||||
"adegokeaanuoluwapo",
|
||||
"abidoyewuraola"
|
||||
],
|
||||
"finished_chunks": [
|
||||
"14-title",
|
||||
|
@ -50,6 +51,19 @@
|
|||
"14-26",
|
||||
"14-28",
|
||||
"14-30",
|
||||
"14-32"
|
||||
"14-32",
|
||||
"14-37",
|
||||
"14-40",
|
||||
"14-43",
|
||||
"14-47",
|
||||
"14-51",
|
||||
"14-53",
|
||||
"14-55",
|
||||
"14-57",
|
||||
"14-60",
|
||||
"14-63",
|
||||
"14-66",
|
||||
"14-69",
|
||||
"14-71"
|
||||
]
|
||||
}
|
Loading…
Reference in New Issue