Tue Feb 27 2018 11:57:58 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2018-02-27 11:57:58 +01:00
parent d973b85b7f
commit 982c988923
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\c 6 \v 1 O si jade lo si ilu abinibi re, awon omo eyin re si te le. Nigbati odi ojo isin, O nko won ni sinagogu. Opolopo si gbo eko naa, enu si ya won. Won si bere wipe, nibo ni o ti gbo gbogbo eko ti on ko ni yi? Iru ogbon wo ni afi fun yi? Iru awon ise iyanu wo ni on fi owo re se wonyi? Se bi gbenagbena ni, omo bibi Maria, ti awon arakunrin je Jemisi, Juda, Simoni ati Josi. Sebi awon arabirin re ngbe pelu wa? Won si binu si Jesu. \c 6 \v 1 O si jade lo si ilu abinibi re, awon omo eyin Re si te le. \v 2 Nigbati odi ojo isin, O nko won ni sinagogu. Opolopo si gbo eko naa, enu si ya won. Won si bere wipe, nibo ni o ti gbo gbogbo eko ti on ko ni yi? Iru ogbon wo ni afi fun yi? Iru awon ise iyanu wo ni on fi owo re se wonyi? \v 3 Se bi gbenagbena ni, omo bibi Maria, ti awon arakunrin je Jemisi, Juda, Simoni ati Josi. Sebi awon arabirin re ngbe pelu wa? Won si binu si Jesu.