Wed May 15 2019 13:03:00 GMT-0900 (Alaskan Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-15 13:03:01 -09:00
parent 79e03c09b1
commit 9475198f7e
2 changed files with 3 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 32 Wọ́n wà lójú ọ̀nà wọ́n ńlọ sí Jèrúsálẹ̀mù, Jésù sí ńlọ níwájú wọn. Ẹnú ya àwọn ọmọ ẹ̀yìn, àti àwọn tí ò ǹtẹ̀le wọn lẹ́yìn ni ẹ̀rù síì ńbà. Lẹ́yìn náà Jésù mú àwọn méjìlá sí ẹ̀gbẹ́ kan ó sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ fún wọn ohun tí yóò sẹlẹ̀ sí òun ní kòpẹ́kòpẹ́. \v 33 "wòó, àwa ńgòkè lọ sí Jèrúsálẹ̀mù, a ó sì fi ọmọ ènìyàn lé àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé lọ́wọ́. Wọn ó dáa lẹ́bi ikú wọn ó sì fi lé àwọn kèfèrí lọ́wọ́. \v 34 Wọn ó fi se ẹlẹ́yà, wọn ó tu itọ́ sí lára, wọn ó nàá pẹ̀lú ẹgba, wọn ó sì paá. Sùgbọ́n lẹ́yìn ọjọ́ kẹta yó j
\v 32 Wọ́n wà lójú ọ̀nà wọ́n ńlọ sí Jèrúsálẹ̀mù, Jésù sí ńlọ níwájú wọn. Ẹnú ya àwọn ọmọ ẹ̀yìn, àti àwọn tí ò ǹtẹ̀le wọn lẹ́yìn ni ẹ̀rù síì ńbà. Lẹ́yìn náà Jésù mú àwọn méjìlá sí ẹ̀gbẹ́ kan ó sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ fún wọn ohun tí yóò sẹlẹ̀ sí òun ní kòpẹ́kòpẹ́. \v 33 "wòó, àwa ńgòkè lọ sí Jèrúsálẹ̀mù, a ó sì fi ọmọ ènìyàn lé àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé lọ́wọ́. Wọn ó dáa lẹ́bi ikú wọn ó sì fi lé àwọn kèfèrí lọ́wọ́. \v 34 Wọn ó fi se ẹlẹ́yà, wọn ó tu itọ́ sí lára, wọn ó nàá pẹ̀lú ẹgba, wọn ó sì paá. Sùgbọ́n lẹ́yìn ọjọ́ kẹ̀ta yó dìde

View File

@ -47,6 +47,7 @@
"10-20",
"10-23",
"10-26",
"10-29"
"10-29",
"10-32"
]
}