Fri Nov 08 2019 21:05:46 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
EDUNOLAOLUWA 2019-11-08 21:05:47 +01:00
parent 0793aa1264
commit 90d69317c3
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Nítorí Jòhánù bá Hẹ́rọ́dù wí, "pé kò tọ̀nà láti yan aya arákùnrin rẹ̀ lálè." \v 19 Hẹrọdíà sì bínú sí Jòhánù, ó sì ń wá ọ̀nà láti pa á, èyí sì nira fún \v 20 nítorí Hẹ́rọ̀dù bẹ̀ru Jòhánù. Àti wípé ó mọ̀n pé olódodo àti ènìyn mimo ni, o si pa a mo. Gbigbo oro re ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo.
\v 18 Nítorí Jòhánù bá Hẹ́rọ́dù wí, "pé kò tọ̀nà láti yan aya arákùnrin rẹ̀ lálè." \v 19 Hẹrọdíà sì bínú sí Jòhánù, ó sì ń wá ọ̀nà láti pa á, èyí sì nira fún \v 20 nítorí Hẹ́rọ̀dù bẹ̀ru Jòhánù. Àti wípé ó mọ̀n pé olódodo àti ènìyan mímó ni, ó sì pa á mọ́n. Gbígbọ́ ọ̀rọ rẹ̀ má ń bíi nínú, sùgbọ́n ó má n fi ayọ̀ gboo.