Fri May 17 2019 08:11:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 08:11:20 +01:00
parent e291ea82fe
commit 8e31dcf0eb
3 changed files with 2 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Ẹ wà ní ìgbáradì. Nwọn ó jọ̀wọ́ yín fún àwọn ìjòyè, a ó sì nà yín ní àwọn sínágógù. Ẹ̀yin yíò dúró ní iwájú àwọn gómìnà ati àwọn ọba nítorí mi, bi ẹ̀rí fún wọn. \v 10 Ṣùgbọ́n a kọ́kọ́ kéde ìhìnrere ní gbogbo orílẹ̀-èdè.
\v 9 Ẹ wà ní ìgbáradì. Nwọn ó jọ̀wọ́ yín fún àwọn ìjòyè, a ó sì nà yín nínú àwọn sínágógù. Ẹ̀yin yóò dúró ní iwájú àwọn gómìnà ati àwọn ọba nítorí mi, bi ẹ̀rí fún wọn. \v 10 Ṣùgbọ́n a kọ́kọ́ kéde ìhìnrere ní gbogbo orílẹ̀-èdè.

View File

@ -1 +1 @@
\v 11 Nígbàtí a bá mu yiń tí a sì jọ̀wọ́ yiń lọ́wọ́, ẹ má ṣe ṣàníyàn oun tí ẹ̀yin yíó sọ. Nítorí ní wákàtí náà, a ó fún yiń ní oun tí ẹ̀yin yíò sọ; ki yíò jẹ́ ẹ̀yin ni yíò sọ̀rọ̀, bíkòṣe Ẹ̀mí Mímọ́. \v 12 Arákùnrin yio jọ̀wọ́ arákùnrin fún ikú, àti bàbá, ọmọ rẹ̀ẹ̀. Àwọn ọmọ yio dìde sí àwọn òbi wọn, nwọn o sì sọwọ́n di ẹni tí ikú npa. \v 13 Gbogbo ènìyàn ni yíò kórira yín nítorí orúkọ mi. Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá forí tì í dópin, ẹni náà yíó yè.
\v 11 Nígbàtí a bá mu yiń tí a sì jọ̀wọ́ yiń lọ́wọ́, ẹ má ṣe ṣàníyàn oun tí ẹ̀yin yíó sọ. Nítorí ní wákàtí náà, a ó fún yiń ní oun tí ẹ̀yin yóò sọ; ki yíò jẹ́ ẹ̀yin ni yóò sọ̀rọ̀, bíkòṣe Ẹ̀mí Mímọ́. \v 12 Arákùnrin yio jọ̀wọ́ arákùnrin fún ikú, àti bàbá, ọmọ rẹ̀ẹ̀. Àwọn ọmọ yio dìde sí àwọn òbi wọn, nwọn o sì sọwọ́n di ẹni tí ikú npa. \v 13 Gbogbo ènìyàn ni yíò kórira yín nítorí orúkọ mi. Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá forí tì í dópin, ẹni náà yíó yè.

View File

@ -41,7 +41,6 @@
"13-05",
"13-07",
"13-09",
"13-11",
"13-14",
"13-17",
"13-21",