Thu May 16 2019 12:29:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:29:35 +01:00
parent 72176927e8
commit 878b01008e
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 20 Wọ́n mú ọmọkùnrin náà wá sọ́dọ̀ rẹ̀, nígbàtí ẹ̀mí náà rí Jésù, ó jẹ́ kí gììrì ki ọmọ náà lójijì. Ọmọkùnrin náà subú lulẹ̀ ó sì ń pòfóló. yọ èfó lẹ́nu rẹ̀. \v 21 Jésù bá bi bàbá ọmọ náà, "Ó ti pẹ́ tó tí ti wà nírú ipò yìí?" Bàbá rẹ̀ dáhùn ówípé, "Láti ìgb` èwe rẹ̀ ni. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, \v 22 ó tilẹ̀ má n gbe jù sínú iná tàbí sínú omi láti paá lára nígbàmíràn. Bí o bá le se ohunkóhun, sàánú fún wa kí o sì rànwálọ́wọ́."
\v 20 Wọ́n mú ọmọkùnrin náà wá sọ́dọ̀ rẹ̀, nígbàtí ẹ̀mí náà rí Jésù, ó jẹ́ kí gììrì ki ọmọ náà lójijì. Ọmọkùnrin náà ṣubú lulẹ̀ ó sì ń pòfóló. \v 21 Jésù bá bi bàbá ọmọ náà, "Ó ti pẹ́ tó tí ti wà nírú ipò yìí?" Bàbá rẹ̀ dáhùn ówípé, "Láti ìgbà èwe rẹ̀ ni. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, \v 22 ó tilẹ̀ má n gbe jù sínú iná tàbí sínú omi láti paá lára nígbà míràn. Bí O bá le se ohun kóhun, sàánú fún wa kí o sì ràn wá lọ́wọ́."