diff --git a/09/47.txt b/09/47.txt index ee30041..8dfdcfe 100644 --- a/09/47.txt +++ b/09/47.txt @@ -1 +1 @@ -\v 47 Bí ojú rẹ kan bá mú ọ kọsẹ̀, yọọ́ dànù. Nítorí ó sàn fún ọ láti wọ Ìjọba ọ̀run pẹ̀lú ojú kan jù kí o ní ojú méjèèjì kí á sì gbe ọ sọ sínú iná ọ̀run àpáàdì, \v 48 níbití ìpáàrà won kììkú, bẹ́ẹ̀ni iná won kììkú. \ No newline at end of file +\v 47 Bí ojú rẹ kan bá mú ọ kọsẹ̀, yọọ́ dànù. Nítorí ó sàn fún ọ láti wọ Ìjọba ọ̀run pẹ̀lú ojú kan jù kí o ní ojú méjèèjì kí á sì gbe ọ sọ sínú iná ọ̀run àpáàdì, \v 48 níbití ìpáàrà wọn kììkú, bẹ́ẹ̀ni iná wọn kììkú. \ No newline at end of file diff --git a/09/49.txt b/09/49.txt index 1ca378f..a396951 100644 --- a/09/49.txt +++ b/09/49.txt @@ -1 +1 @@ -\v 49 Nítorí olúkúlùkù ni a o fi iyọ̀ mún dùn pẹ̀lú iná. \v 50 Iyọ̀ dára, sùgbọ́n bí iyọ̀ bá sọ adùn rẹ̀ nùn, báwo ni a o se mún dùn padà? Ẹní iyọ̀ láàrin ara yín, ki ẹ sì wà ní àlàíà pẹ̀lú ara yín." \ No newline at end of file +\v 49 Nítorí olúkúlùkù ni a o fi iyọ̀ mú dùn pẹ̀lú iná. \v 50 Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n bí iyọ̀ bá sọ adùn rẹ̀ nù, báwo ni a o ṣe mú dùn padà? Ẹní iyọ̀ láàrin ara yín, ki ẹ sì wà ní àlàáfsíà pẹ̀lú ara yín." \ No newline at end of file