Thu May 20 2021 14:22:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 14:22:13 +01:00
parent f386705c25
commit 824d04b64a
1 changed files with 1 additions and 2 deletions

View File

@ -1,2 +1 @@
\v 6 “Ìránṣẹ́ kan ṣoṣo ló kù tí Baba olóko kò ì tí ì rán níṣẹ́, èyí ni ọmọ òun tìkára rẹ̀. Níkẹyìn ó ran an sí àwọn olùṣọ́gbà náà, pẹ̀lú èrò pé, Wọn yóò bu ọlá fún ọmọ òun.
7 “Ṣùgbọ́n àwọn olùṣọ́gbà wọ̀n-ọn-nì wí fún ara wọn pé, Èyí yìí ni àrólé. Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a pa á, ogún rẹ̀ yóò sì jẹ́ tiwa. \v 7 ff
\v 6 “Ó ní ẹnìkan síi láti rán, èyí ni àyànfẹ́ ọmọ rẹ̀. Níkẹyìn ó ran an sí àwọn olùṣọ́gbà náà. Ó wípé, Wọn yóò bu ọlá fún ọmọ mi. \v 7 “Ṣùgbọ́n àwọn olùṣọ́gbà wọ̀n-ọn-nì wí fún ara wọn pé, Èyí yìí ni àrólé. Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a pa á, ogún rẹ̀ yóò sì jẹ́ tiwa.